Dataset Viewer
Auto-converted to Parquet
sentence
stringlengths
21
391
Ọmọ ẹgbẹ́ òkùnkùn dèrò àtìmọ́lé torí nílùú Ìbàdàn.
Ìyàwó àwọn ọlọ́pàá tó kú lásìkò ìwọ́de tó kọjá ti bẹ̀bẹ̀ fún ìrànwọ́
Nítori ọrọ táa sọ lọ́jọ́sí ni Túndé yoo fi kúrò nílé ìwé.
Ilẹ̀ mímìtìtì ní ìlú ṣakí ti sọ àwọn olugbé ibẹ̀ sínú hílàhílo
Ìgbòho ní Aláàfin, Ọ̀ọ̀nì, Olúbàdàn tì òun lẹ́yìn.
Àfáà ń wáàsù kí àwọn alátìlẹ́yìn rẹ̀ má gba abẹ́rẹ́ àjẹ́sára.
Awọn gómìnà kankan ti padà sí ẹgbẹ́ òṣèlú onígbàálẹ̀.
Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló fẹ́ kúrò nílè Nàíjíríà.
Ọba ìlú wa kìlọ̀ fún áwọn ọ̀dọ́ lórí ṣíṣe òògùn owó òjijì.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọ̀dọ́ lọ́ fẹ́ fi orílẹ̀ èdè Nàìjíríà sílẹ̀.
Àwọn àjẹ́ ló wà nídí ọ̀rọ̀ Àrẹ̀mú.
Oṣù kan péré ni Àjídé fi ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Adélékè.
Àtisùn ti dogun torí ọ̀rọ̀ àbò ní orílẹ-èdè yìí.
Ìwádìí fi hàn pé ikú àrá ló pa àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba mẹ́ta kan.
Àwọn ẹ̀yà Yorùbá máa ń pé ara wọn ní ọmọ ilẹ̀ káàárọ̀-ò-jíire.
Ẹgbọ́n mi ni Ọlápọ̀si, ó ní ìyàwó méjì, àti ọmọ mẹ́ta.
Ọ̀rẹ́bìnrin méjì ti para wọn torí wọ́n ba ọkọ ara wọn sùn.
Ajá mẹ́ta ló ń ṣọ́ ilé ọ̀gá ọlọ́pàá tó wà ní Yemẹtu Ìbàdàn
Ẹ̀sùn bíbá ọmọdé tage kò yẹ àgbàlagbà ọkùnrin
Àwọn ìlànà yìí yóó ṣe ìrànwọ́ fún àwọn ènìyàn.
Ìjà wọn ò ṣeé dá sí kí wọn má baà yi lé èèyàn lórí.
Ó jọ bí ẹni pé alága ẹgbẹ́ Iréwọlédé ni Ọlátúndé Adégbuyì
Ṣèyí fojú hàn n'íta fún ìgbà àkọ́kọ́ lẹ́yìn tó ṣẹ́gun ọ̀tá.
Ìjọba Ọ̀sun ní abẹ́rẹ́ àjẹsára lọ́wọ́.
Bùnmi tún parọ́ pé òun kọ́ lòun wa ọkọ̀ sáré àsájù.
Gbogbo àwọn ọmọbìnrin ló nílò ìtọ́jú tó dára.
Àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba ti ń kọ́ àwọn èèyàn bí wọ́n ṣe lè dìbò
Iṣẹ́ àgbẹ̀ ṣe kókó lásìkò yìí.
Ǹjẹ́ o mọ̀ nípa Bídèmí tó wọ gàu ní Amẹ́ríkà lórí ẹ̀sùn jì̀bì̀tì̀
Àwọn adarí ilé iṣẹ́ náà ni ó ń fa wàhálà fún àwọn òṣìṣẹ́ náà.
Kò séwu fún gbogbo àwọn tí yóò kópa nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ní Èkó.
Ìforúkọ sílẹ̀ ti ń lọ lórí ayélujára láti di ọlọ́pàá.
Ohun tó ṣẹlẹ̀ níbi àjọ̀dún ẹgbẹ́ wa kọ́wa lọ́gbọ́n gidigidi.
Ẹgbẹ́ ọlọ́dẹ pariwo síta lórí ìlànà ìgbanisíṣẹ́ ìjọba.
Mó mu àwọn àlàyé àti ìmọ̀ràn yí ni pàtàkì nínú ìgbésí ayé mi.
Wọ́n sọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ níbi ètò tí mo lọ lọ́jọ́ ìsinmi tó kọjá
Adìyẹ kan yàgbé sí orí ọkọ̀ mi.
Ọlá ń kírun lọ́wọ́ ni wọ́n ta ní ìbọn.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti kó ẹgbẹ̀rún ìrẹsì fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba.
Adédoyin ló ni ilé ìtura tó wà lọ́nà Yemẹtu ní Ìbàdàn
Ìpàdé ìdìbò ẹgbẹ́ òṣèlú wa máa wáyé ní ìlú Ìsánlú lọ́túnla
Àwọn ọlọ́sìn ẹja ní àìríṣẹ́ṣe ló fà gbogbo oun tó ṣẹlẹ̀.
Èèyàn mẹ́rin kú ní Nàíjíríà lónìí.
Ta ló fipá bá Fúnkẹ́ lò pọ̀ ní ìlú Ọ̀ṣun?
Babaláwo Ìgbòho sọ pé àwọn agbófinró ti gbé aṣọ òun lọ.
Ìjà wáyé láàrin ọ̀rẹ́ tímọ́-tímọ́ méjì.
Bọ̀sú ti padà yọjú sí àgọ́ ọlọ́pàá lẹ́yìn tí wọ́n ráṣẹ́ pè é.
Ó ní kí ìjọba àpapọ̀ náà ṣé àtúnṣe.
Kì í ṣe nǹkan tuntun kí agbábọ́ọ̀lù kú sórí pápá.
Ìyáàfin Olúwalóní ti bèèrè fún owó ìtanràn lọ́wọ́ ọlọ́pàá.
Ilé-ìwé gíga Èkó ti gba Bùsáyọ̀ wọlé.
Àwọn mẹ́fà kú nínú àwọn sójà tí ó lọ jà fún ìlú.
Ewu wo làwọn òṣìṣẹ́ elétò ìlèra ń kojú ní Nàìjíríà?
Ikú ààrẹ̀ ìjọ́sí jẹ́ oun tó dun gbogbo ìlú gidigidi.
Bọ́lá fẹ́ ja mí lólè, ṣùgbọ́n Ọlọ́run kò gbà fún-un
Bàbá mi kọ̀ láti bá mi sọ̀rọ̀ torí ọ̀kọ akáta tí mo mú wálé
Wọ́n gbà pé owó ni àwọn ará Èkó ń lé, wọn kò ní Ọlọ́run.
Àwọn ọ̀dọ́ ìlú Ọ̀ffa fàákékọ́rí lórí ìwọ́de náà.
Àwọn olórin tún máa ń mọ ìtàn nípa èèyàn, ìdílé àti ìlú lápapọ̀.
Ẹyọ kan ṣoṣo ló wá láti tọ̀jú aláìsàn nínú àwọn òṣìṣẹ́ náà.
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti gbé ìlànà mìíràn láti fi ṣe ìsìnkú ọba.
Ọ̀dọ̀ fásitì kan ní ìlú Èkó ló ṣe òògùn ìtura yìí.
Ọlọ̀pàá yin àwọn aráàlú tí wọ́n kígbe síta.
Nkò le ṣeré pẹ̀lú ọkùnrin tí mi ò mọ rí lẹ́yìn ìgbeyàwó mi
Ọkọ ọbabìnrin ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sí àti àwọn ọmọ rẹ̀ ni wọ́n pé jọ
Báwo ni àwọn ikọ̀ yìí yóó ṣe dáná sun ara wọn?
Wọ́n má ń fipá bá obìnrin kan lòpò láàárín wákàtí mẹ́ta.
Ọmọ tó bí sọ́gbà ẹ̀wọ̀n ló kọ̀kọ́ gba ẹ̀bùn ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́.
Àwọn ọmọ náà jẹ àgbàdo lójú títì.
Ẹni tó dábàá èlé owó epo ti tún bá ìjọba já nítorí àríyànjiyàn
Ìgbà tí wọ́n dé Ìbàdàn, wọ́n kọ́ ilé sí agbègbè Mọ̀lété.
Iṣẹ́ ti bẹ̀rẹ̀ ní pẹrẹu fún Àmọ̀tẹ́kùn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.
Ọ̀lọ́pàá sọ pé ìjọba àpapọ̀ kò ran àwọn lọ́wọ́ tó bó ṣe yẹ
Alágbádá ti gbóṣùbà fún Gbóyèga Fámọdún kó tó gbée lọ sílé ẹjọ́
Tàlàbí ní ìwọ́de kọ́ ni Ààrẹ ọ̀nà Kakańfò fi ń bẹ̀rẹ̀ ogun.
Ilé aṣòfin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti wó.
Àwọn Adigunjàlè kọlu ilé-ìfowópamọ́ ní Ọṣun.
Ṣèyí Mákindé ti yọ àwọn olùkọ́ kúrò nípò.
Mo ti gbà fún Ọlọ́run níbi tí mo wà báyìí ni Ìgbòho sọ.
Àwọn jàndùkú jí agbábọ́ọ̀lù Nàìjíríà méjì gbé lópòpónà.
Ìjọba àpapọ̀ ti ra abẹ́rẹ́ àjẹsára onígbá méjì ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá.
Ìyà ló ń jẹ àwọn nọ́ọ̀sì ní Ọ̀wọ̀ tí wọ́n fi ń bínú.
Ẹni ṣiṣẹ́ jàre ìṣẹ́ ni àwọn Yorùbá máa ń wí.
Àwọn àwòrán tí wọ́n yà níbi ìgbéyàwó ọmọ ààrẹ kò dára.
Jọ̀wọ́ bá mi kí ìyá wa pẹ̀lú ọmọ pupa mi, Oyindàmọ́lá.
Ó ṣe pàtàkì fún gbogbo ọmọ ìlú lái dìbò yan aṣojú wọn.
Ọkùnrin méjì ló fi mágùn sí orí ìyàwó rẹ̀ ní Bashọ̀run
Ẹlòmíìran ń fi irú ọyàn wa tọrọ.
Àjọ aṣọ́nà kìlọ̀ f'áwọn awakọ̀ tó máa tẹ fóònù lórí ìrin ní Èkó.
Gómìnà Bùkọ́lá fún Dókítà ní àmì ẹ̀yẹ fún ìṣẹ́ takuntakun.
Ìdájọ́ òdodo nìkan ni mò ń bèèrè fún lórí ọ̀rọ̀ Bàbá Ìjẹ̀ṣà.
Kò sí ààyè láti fẹ́ran Akérédolú ju Arígbábuwó lọ
Ọ̀rẹ́ bí ọmọ ìyá ni èmi àti Ìfẹ́dọ̀lápọ̀, alábáárò mi ni ó ń ṣe.
Ọmọ ọdún mẹ́tàdínláàdọ́ta kan ló pa ọkọ ẹ̀ nítorí owó
Tọ́lá tún wá sí ààfin láìmú ọkọ wá.
O ti tó àádọ́ta ọdún tí a ti fi ẹ̀sùn kan Ìgbòho àti Káyọ̀dé
Àwọn agbénipa tí wọ́n jí ọmọ náà gbé ní ojú pópó lásán ló paá
Àlékún bá iye owó búrẹ́dì ní ìlú Èrúwà.
Kí gan-an láwọn nǹkan tó n fa àìsàn ibà ní àgọ̀-ara?
Dọ́kítà kan ti sọ àwọn ìdí tí obìnrin fi dára ju ọkùnrin lọ.
End of preview. Expand in Data Studio
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
86